Àwọn Adájọ́ 1:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà bá fi ọ̀nà tí wọn ń gbà wọ ìlú náà hàn wọ́n, wọ́n bá fi idà pa gbogbo àwọn ará ìlú náà, ṣugbọn wọ́n jẹ́ kí ọkunrin náà ati gbogbo ìdílé rẹ̀ jáde lọ.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:18-32