Àwọn Adájọ́ 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn amí náà rí ọkunrin kan tí ń jáde bọ̀ láti inú ìlú náà, wọ́n wí fún un pé, “Jọ̀wọ́, fi ọ̀nà tí a óo gbà wọ ìlú yìí hàn wá, a óo sì ṣe ọ́ lóore.”

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:18-28