Àwọn Adájọ́ 1:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin náà lọ sí ilẹ̀ àwọn ará Hiti, ó tẹ ìlú kan dó, ó sì sọ ọ́ ní Lusi. Orúkọ náà ni wọ́n ń pe ìlú náà títí di òní olónìí.

Àwọn Adájọ́ 1

Àwọn Adájọ́ 1:18-32