Aisaya 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n da aṣọ ọ̀fọ̀ bora ní ìta gbangba.Gbogbo wọn dúró lórí òrùlé ilé wọn,ati ní gbogbo gbàgede, wọ́n ń pohùnréré ẹkún,omijé sì ń dà lójú wọn.

Aisaya 15

Aisaya 15:1-5