Aisaya 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọbinrin Diboni ti gun àwọn ibi pẹpẹ tí wọ́n ti ń bọ̀rìṣà lọ, wọ́n lọ sọkún.Moabu ń pohùnréré ẹkún nítorí Nebo ati Medeba.Gbogbo orí wọn pá, wọ́n sì ti fá gbogbo irùngbọ̀n wọn.

Aisaya 15

Aisaya 15:1-3