Aisaya 15:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ tí OLUWA sọ nípa ilẹ̀ Moabu nìyí:Nítorí tí a wó ìlú Ari ati Kiri lulẹ̀ ní òru ọjọ́ kan ṣoṣo,ó parí fún Moabu.

Aisaya 15

Aisaya 15:1-5