Aisaya 15:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Heṣiboni ati Eleale ń kígbe lóhùn rara,àwọn ará Jahasi gbọ́ ariwo wọn;nítorí náà àwọn ọmọ ogun Moabu sọkún,ọkàn rẹ̀ sì wárìrì.

Aisaya 15

Aisaya 15:1-9