Ṣugbọn àwọn ẹranko ní yóo máa sùn níbẹ̀ilé rẹ̀ yóo sì kún fún ẹyẹ òwìwí,ògòǹgò yóo máa gbè ibẹ̀ẹhànnà òbúkọ yóo sì máa ta pọ́núnpọ́nún káàkiri ibẹ̀.