Ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀ láti ìran dé ìran,àwọn ará Arabia kankan kò ní pa àgọ́ sibẹ,bẹ́ẹ̀ ni àwọn darandaran kankan kò ní jẹ́ kí agbo aguntan wọn sinmi níbẹ̀.