Aisaya 13:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìkookò yóo máa ké ninu ilé ìṣọ́ rẹ̀,ààfin rẹ̀ yóo di ibùgbé àwọn ajáko,àkókò rẹ̀ súnmọ́ etílé,ọjọ́ rẹ̀ kò sì ní pẹ́ mọ́.

Aisaya 13

Aisaya 13:16-22