Aisaya 11:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà tí ó gbòòrò yóo wà láti Asiria, fún ìyókù àwọn eniyan rẹ̀;bí ó ti ṣe wà fún àwọn ọmọ Israẹli,nígbà tí wọn ń bọ̀ láti Ijipti.

Aisaya 11

Aisaya 11:15-16