Aisaya 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo pa Ijipti run patapata.Yóo na ọwọ́ ìjì líle sí orí odò Pirati,yóo sì pín in sí ọ̀nà meje,kí àwọn eniyan lè máa ríbi là á kọjá.

Aisaya 11

Aisaya 11:8-16