Aisaya 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

O óo sọ ní ọjọ́ náà pé,“N óo fi ọpẹ́ fún OLUWA,nítorí pé bí ó tilẹ̀ bínú sí mi,inú rẹ̀ ti rọ̀, ó sì tù mí ninu.

Aisaya 12

Aisaya 12:1-6