Òwe 25:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí o ti fi ojú ara rẹ rímá ṣe kánjú gbé e lọ sílé ẹjọ́ nítorí kí ni ìwọ yóò ṣe ní ìgbẹ̀yìnbí aládùúgbò rẹ bá dójú tì ọ́?

Òwe 25

Òwe 25:1-18