Òwe 25:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá ń ṣe àwíjàre rẹ níwájú aládùúgbò rẹ,má ṣe tú àsírí tí ẹlòmíràn ní lọ́dọ̀ rẹ,

Òwe 25

Òwe 25:1-18