Òwe 25:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sàn kí ó wí fún ọ pé, “Gòkè wá síhìn ín”ju wí pé kí ó dójú tì ọ́ níwájú ènìyàn pàtàkì.

Òwe 25

Òwe 25:2-17