Òwe 13:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọlọ́gbọ́n ọmọ pa àṣẹ baba rẹ̀ mọ́ṣùgbọ́n ẹlẹ́gàn kò fetí sí ìbáwí.

2. Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ènìyàn ń gbádùn àwọn ohun rereṣùgbọ́n, aláìsòótọ́ ní ìfẹ́ ọkàn láti inú ìwà ipá.

3. Ẹnikẹ́ni tí ó ṣọ́ ẹnu rẹ̀ pa ẹnu ara rẹ̀ mọ́,ṣùgbọ́n ẹni tí ó ń sọ̀rọ̀ gbàù-gbàù yóò parun.

4. Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkankan,ṣùgbọ́n ọkàn àwọn ti kì í ṣọ̀lẹ rí ìtẹ́lọ́rùn.

Òwe 13