Òwe 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́gbọ́n ọmọ pa àṣẹ baba rẹ̀ mọ́ṣùgbọ́n ẹlẹ́gàn kò fetí sí ìbáwí.

Òwe 13

Òwe 13:1-3