Òwe 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkankan,ṣùgbọ́n ọkàn àwọn ti kì í ṣọ̀lẹ rí ìtẹ́lọ́rùn.

Òwe 13

Òwe 13:1-12