Nehemáyà 13:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo pàṣẹ kí wọn ya àwọn iyàrá náà sí mímọ́, mo sì kó àwọn ohun èlò ilé Ọlọ́run padà síbẹ̀ pẹ̀lú ọrẹ ọkà àti tùràrí.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:1-14