Nehemáyà 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì tún gbọ́ pé, kò fi àwọn ìpín tí a yà sọ́tọ̀ fún àwọn Léfì, àwọn akọrin tí ń ṣe àkóso ìsìn sì ti padà sí ẹnu onírúurú iṣẹ́ẹ wọn.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:7-14