Nehemáyà 13:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò tẹ́ mi lọ́rùn rárá, mo kó gbogbo ohun èlò ìdílée Tóbíyà dà síta láti inú iyàrá náà.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:1-14