Nehemáyà 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì padà sí Jérúsálẹ́mù. Níhìn-ín ni mo ti mọ̀ nípa onírúurú ohun búburú tí Élíásíbù ti ṣe ní ti pípèṣè yàrá fún Tóbíyà nínú àgbàlá ilé Ọlọ́run.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:1-15