Mátíù 27:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn isà òkú sì sí sílẹ̀. Ọ̀pọ̀ àwọn olódodo ọkùnrin àti obìnrin tí ó ti kú sì tún jíǹde.

Mátíù 27

Mátíù 27:45-61