Mátíù 27:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójú kan náà aṣọ ìkélé tẹ̀ḿpìlì fàya, láti òkè dé ìsàlẹ̀. Ilẹ̀ sì mì tìtì. Àwọn àpáta sì sán.

Mátíù 27

Mátíù 27:47-60