Mátíù 27:53 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n jáde wá láti isà òkú lẹ́yìn àjíǹde Jésù, wọ́n sì lọ sí ìlú mímọ́. Níbẹ̀ ni wọ́n ti fi ara han ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Mátíù 27

Mátíù 27:47-54