Mátíù 13:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òwe ni Jésù fi sọ nǹkan wọ̀nyí fún àwọn ènìyàn, òwe ni ó fi bá wọn sọ gbogbo ọ̀rọ̀ tó sọ.

Mátíù 13

Mátíù 13:24-38