Mátíù 13:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ọ̀rọ̀ tí a ti ẹnu àwọn wòlíì sọ lé wá sí ìmúsẹ pé:“Èmi yóò ya ẹnu mi láti fi òwe sọ̀rọ̀.Èmi yóò sọ àwọn ohun tí ó farasin láti ìpilẹ̀ṣẹ̀ ayé wá.”

Mátíù 13

Mátíù 13:30-36