Mátíù 13:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó tún pa òwe mìíràn fún wọn: “Ìjọba ọ̀run dàbí yíìsìtì tí obìnrin kan mú tí ó pò mọ́ ìyẹ̀fun (ìyẹ̀fun) púpọ̀ títí tí gbogbo rẹ fi di wíwú.”

Mátíù 13

Mátíù 13:25-34