Máàkù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀, àwọn olórí àlùfáà, àwọn àgbààgbà, àwọn alùkọ́ òfin àti gbogbo àjọ ìgbìmọ̀ fi ẹnu kò lórí ohun tí wọn yóò ṣe. Wọ́n sì de Jésù, wọ́n mú un lọ, wọ́n sì fi lé Pílátù lọ́wọ́.

Máàkù 15

Máàkù 15:1-8