Máàkù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù sì bi í léèrè, ó ni, “Ṣe ìwọ ni ọba àwọn Júù?”Jésù sì dáhùn pé, “Ìwọ wí.”

Máàkù 15

Máàkù 15:1-9