Máàkù 1:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù kún fún àánú, ó na ọwọ́ rẹ̀, ó fi ọwọ́ rẹ̀ bà a, ó wí pé, “Èmí fẹ́. Di mímọ́.”

Máàkù 1

Máàkù 1:39-45