Máàkù 1:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin adẹ́tẹ̀ kan tọ̀ ọ́ wá, ó sì kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀. Ó sì bẹ̀bẹ̀ fún ìmúláradà. Ó wí pé, “Bí ìwọ bá fẹ́, ìwọ lè mú mi láradá.”

Máàkù 1

Máàkù 1:35-45