Máàkù 1:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lójúkan-náà ẹ̀tẹ̀ náà fi sílẹ̀ lọ, ọkùnrin náà sì rí ìwòsàn.

Máàkù 1

Máàkù 1:36-45