Jóòbù 42:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sọ orúkọ àkọ̀bí ní Jẹ́mímà, àti orúkọ èkejì ni Késíà àti orúkọ ẹ̀kẹta ní Kérén-hápúkì.

Jóòbù 42

Jóòbù 42:11-17