Jóòbù 42:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ní gbogbo ilẹ̀ náà, a kò rí obìnrin tí ó ní ẹwà bí ọmọ Jóòbù; baba wọ́n sì pínlẹ̀ fún wọn ninú àwọn arákùnrin wọn.

Jóòbù 42

Jóòbù 42:7-17