Deutarónómì 29:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ ọ̀ rẹ àti ìyàwó ò rẹ àti àwọn àlejò tí wọ́n ń gbé ní àgọ́ ọ̀ rẹ, tí ó ké pópòpó igi rẹ, tí ó sì gbé omi ì rẹ.

Deutarónómì 29

Deutarónómì 29:3-17