Deutarónómì 29:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo yín ń dúró lónìí yìí níwájú Olúwa Ọlọ́run rẹ: adarí ì rẹ àti olórí àwọn ọkùnrin, àwọn àgbààgbà rẹ àti àwọn olóyè àti gbogbo àwọn ọkùnrin mìíràn ní Ísírẹ́lì,

Deutarónómì 29

Deutarónómì 29:6-18