Deutarónómì 29:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O dúró níhìn ín yìí kí o lè wọ inú májẹ̀mú pẹ̀lú Olúwa Ọlọ́run rẹ, májẹ̀mú tí Olúwa ń ṣe pẹ̀lú ù rẹ lónìí yìí àti tí óun dè pẹ̀lú ìbúra,

Deutarónómì 29

Deutarónómì 29:5-19