Ámósì 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Èmi yóò si tún mú ìgbèkùn Ísírẹ́lì ènìyàn mi padà bọ̀Wọn yóò sì kọ́ ahoro ìlú, wọn yóò sì máa gbé inú wọnWọn yóò sì gbin àjàrà, wọn yóò sì mu ọtí wáìnì wọnwọn yóò sì se ọgbà pẹ̀lú, wọn yóò sì jẹ èso inú wọn