Èmi yóò gbin Ísírẹ́lì sí orí ilẹ̀ rẹ̀.A kì yóò sì fà wọn tu mọ́ láéláékúrò ni orí ilẹ̀ ti mo fi fún wọn,”ni Olúwa Ọlọ́run rẹ wí.