1 Kọ́ríńtì 15:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kíyesí í, ohun ìjìnlẹ̀ ni mo sọ fún un yín: gbogbo wá kì yóò sùn, ṣùgbọ́n gbogbo wá ní a ó paláradà,

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:45-55