1 Kọ́ríńtì 15:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará, ǹjẹ́ èyí ní mo wí pé, ara àti ẹ̀jẹ̀ kò lè jogún Ìjọba Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni ìdíbàjẹ́ kò lé jogún àìdíbàjẹ́.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:43-58