1 Kọ́ríńtì 15:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́gán, ni ìṣẹ́jú kan, nígbà ìpè ìkẹyìn: nítorí ìpè yóò dún, a ó sì jí àwọn òkú dìdé ní àìdíbàjẹ́, a ó sì pa wá láradà.

1 Kọ́ríńtì 15

1 Kọ́ríńtì 15:43-57