Rom 7:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori ohun ti emi nṣe, emi kò mọ̀: nitori ki iṣe ohun ti mo fẹ li emi nṣe; ṣugbọn ohun ti mo korira, li emi nṣe.

Rom 7

Rom 7:10-18