Rom 7:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awa mọ̀ pe ohun ẹmí li ofin: ṣugbọn ẹni ti ara li emi, ti a ti tà sabẹ ofin.

Rom 7

Rom 7:8-16