Rom 3:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NJẸ anfani ki ha ni ti Ju? tabi kini ère ilà kíkọ?

2. Pipọ lọna gbogbo; ekini, nitoripe awọn li a fi ọ̀rọ Ọlọrun le lọwọ.

3. Njẹ ki ha ni bi awọn kan jẹ alaigbagbọ́? aigbagbọ́ wọn yio ha sọ otitọ Ọlọrun di asan bi?

Rom 3