Rom 2:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Ju ti inu ni Ju, ati ikọla ti ọkàn, ninu ẹmi ni, kì iṣe ti ode ara; iyìn ẹniti kò si lọdọ enia, bikoṣe lọdọ Ọlọrun.

Rom 2

Rom 2:27-29