Rom 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nigbati awọn Keferi, ti kò li ofin, ba ṣe ohun ti o wà ninu ofin nipa ẹda, awọn wọnyi ti kò li ofin, jẹ ofin fun ara wọn:

Rom 2

Rom 2:13-23