Rom 2:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori kì iṣe awọn olugbọ ofin li alare lọdọ Ọlọrun, ṣugbọn awọn oluṣe ofin li a o dalare.

Rom 2

Rom 2:6-21